25 Àmọ́ tó bá ti lé ní ẹni àádọ́ta (50) ọdún, kó fẹ̀yìn tì lẹ́nu iṣẹ́ náà, kó sì ṣíwọ́ iṣẹ́. 26 Ó lè máa ṣèrànwọ́ fún àwọn arákùnrin rẹ̀ tí wọ́n ń ṣe ojúṣe wọn nínú àgọ́ ìpàdé, àmọ́ kó má ṣiṣẹ́ níbẹ̀. Ohun tí o máa ṣe nípa àwọn ọmọ Léfì àti ojúṣe+ wọn nìyí.”