ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 1:53
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 53 Kí àwọn ọmọ Léfì sì pàgọ́ yí àgọ́ Ẹ̀rí ká, kí n má bàa bínú sí àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì;+ àwọn ọmọ Léfì ni kó máa bójú tó* àgọ́ ìjọsìn Ẹ̀rí+ náà.”

  • Nọ́ńbà 3:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 Olórí ìjòyè àwọn ọmọ Léfì ni Élíásárì+ ọmọ àlùfáà Áárónì, òun ló ń darí àwọn tó ń bójú tó iṣẹ́ ní ibi mímọ́.

  • Nọ́ńbà 18:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Kí wọ́n dara pọ̀ mọ́ ọ, kí wọ́n sì máa ṣe ojúṣe wọn tó jẹ mọ́ àgọ́ ìpàdé àti gbogbo iṣẹ́ àgọ́ náà, ẹnikẹ́ni tí kò lẹ́tọ̀ọ́* sí i kò sì gbọ́dọ̀ sún mọ́ yín.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́