Nọ́ńbà 1:51 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 51 Nígbàkigbà tí ẹ bá fẹ́ kó àgọ́ ìjọsìn náà kúrò,+ àwọn ọmọ Léfì ni kó tú u palẹ̀; tí ẹ bá sì fẹ́ to àgọ́ ìjọsìn náà pa dà, àwọn ọmọ Léfì ni kó tò ó; tí ẹnikẹ́ni tí kò lẹ́tọ̀ọ́* bá sún mọ́ ọn, ṣe ni kí ẹ pa á.+ Nọ́ńbà 3:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Kí o yan Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀, kí wọ́n máa ṣe iṣẹ́ àlùfáà,+ tí ẹnikẹ́ni tí kò lẹ́tọ̀ọ́* sí i bá sì sún mọ́ tòsí, ṣe ni kí ẹ pa á.”+
51 Nígbàkigbà tí ẹ bá fẹ́ kó àgọ́ ìjọsìn náà kúrò,+ àwọn ọmọ Léfì ni kó tú u palẹ̀; tí ẹ bá sì fẹ́ to àgọ́ ìjọsìn náà pa dà, àwọn ọmọ Léfì ni kó tò ó; tí ẹnikẹ́ni tí kò lẹ́tọ̀ọ́* bá sún mọ́ ọn, ṣe ni kí ẹ pa á.+
10 Kí o yan Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀, kí wọ́n máa ṣe iṣẹ́ àlùfáà,+ tí ẹnikẹ́ni tí kò lẹ́tọ̀ọ́* sí i bá sì sún mọ́ tòsí, ṣe ni kí ẹ pa á.”+