Ẹ́kísódù 40:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Kí o fòróró yàn wọ́n bí o ṣe fòróró yan bàbá wọn,+ kí wọ́n lè di àlùfáà mi, ìran wọn á sì máa ṣiṣẹ́ àlùfáà títí lọ torí o ti fòróró yàn wọ́n.”+ Nọ́ńbà 18:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ojúṣe ìwọ àti àwọn ọmọ rẹ ni láti máa ṣe iṣẹ́ àlùfáà tó jẹ mọ́ pẹpẹ àtàwọn ohun tó wà lẹ́yìn aṣọ ìdábùú,+ ẹ̀yin ni kí ẹ máa ṣe iṣẹ́ yìí.+ Mo ti fi iṣẹ́ àlùfáà ṣe ẹ̀bùn fún yín, ṣe ni kí ẹ pa+ ẹnikẹ́ni tí kò lẹ́tọ̀ọ́* sí i tó bá sún mọ́ tòsí.”
15 Kí o fòróró yàn wọ́n bí o ṣe fòróró yan bàbá wọn,+ kí wọ́n lè di àlùfáà mi, ìran wọn á sì máa ṣiṣẹ́ àlùfáà títí lọ torí o ti fòróró yàn wọ́n.”+
7 Ojúṣe ìwọ àti àwọn ọmọ rẹ ni láti máa ṣe iṣẹ́ àlùfáà tó jẹ mọ́ pẹpẹ àtàwọn ohun tó wà lẹ́yìn aṣọ ìdábùú,+ ẹ̀yin ni kí ẹ máa ṣe iṣẹ́ yìí.+ Mo ti fi iṣẹ́ àlùfáà ṣe ẹ̀bùn fún yín, ṣe ni kí ẹ pa+ ẹnikẹ́ni tí kò lẹ́tọ̀ọ́* sí i tó bá sún mọ́ tòsí.”