Léfítíkù 18:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 “‘O ò gbọ́dọ̀ bá ìyàwó ẹnì kejì rẹ* lò pọ̀ kí o wá tipa bẹ́ẹ̀ sọ ara rẹ di aláìmọ́.+ Diutarónómì 5:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 “‘O ò sì gbọ́dọ̀ ṣe àgbèrè.+