Róòmù 7:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Bí àpẹẹrẹ, òfin de obìnrin tí a gbé níyàwó mọ́ ọkọ rẹ̀ nígbà tí ọkùnrin náà bá wà láàyè; àmọ́ tí ọkọ rẹ̀ bá kú, a dá a sílẹ̀ kúrò lábẹ́ òfin ọkọ rẹ̀.+
2 Bí àpẹẹrẹ, òfin de obìnrin tí a gbé níyàwó mọ́ ọkọ rẹ̀ nígbà tí ọkùnrin náà bá wà láàyè; àmọ́ tí ọkọ rẹ̀ bá kú, a dá a sílẹ̀ kúrò lábẹ́ òfin ọkọ rẹ̀.+