-
Léfítíkù 9:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Áárónì wá kọjú sí àwọn èèyàn náà, ó sì gbé ọwọ́ rẹ̀ sókè, ó súre fún wọn,+ ó sì sọ̀ kalẹ̀ kúrò níbi tó ti ń fi ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀, ẹbọ sísun àti ẹbọ ìrẹ́pọ̀ rúbọ.
-