Sáàmù 29:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Jèhófà yóò fún àwọn èèyàn rẹ̀ ní agbára.+ Jèhófà yóò fi àlàáfíà jíǹkí àwọn èèyàn rẹ̀.+ Lúùkù 2:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 “Ògo ni fún Ọlọ́run ní ibi gíga lókè àti àlàáfíà fún àwọn ẹni ìtẹ́wọ́gbà* ní ayé.”