-
2 Kíróníkà 7:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ọba Sólómọ́nì fi ẹgbẹ̀rún méjìlélógún (22,000) màlúù àti ọ̀kẹ́ mẹ́fà (120,000) àgùntàn rúbọ. Bí ọba àti gbogbo àwọn èèyàn náà ṣe ṣayẹyẹ ṣíṣí ilé Ọlọ́run tòótọ́ nìyẹn.+
-