Ẹ́kísódù 6:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Áárónì wá fi Élíṣébà, ọmọ Ámínádábù, arábìnrin Náṣónì+ ṣe aya. Ó bí Nádábù, Ábíhù, Élíásárì àti Ítámárì+ fún un. Lúùkù 3:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Nǹkan bí ẹni ọgbọ̀n (30) ọdún+ ni Jésù+ nígbà tó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀, bí wọ́n sì ṣe rò, ó jẹ́ ọmọJósẹ́fù,+ọmọ Hélì, Lúùkù 3:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 ọmọ Ámínádábù,ọmọ Áánì,ọmọ Hésírónì,ọmọ Pérésì,+ọmọ Júdà,+ Yorùbá Publications (1987-2025) Jáde Wọlé Yorùbá Fi Ráńṣẹ́ Èyí tí mo fẹ́ràn jù Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania Àdéhùn Nípa Lílò Òfin Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ JW.ORG Wọlé Fi Ráńṣẹ́ Fi Ráńṣẹ́ Lórí Email
23 Áárónì wá fi Élíṣébà, ọmọ Ámínádábù, arábìnrin Náṣónì+ ṣe aya. Ó bí Nádábù, Ábíhù, Élíásárì àti Ítámárì+ fún un.
23 Nǹkan bí ẹni ọgbọ̀n (30) ọdún+ ni Jésù+ nígbà tó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀, bí wọ́n sì ṣe rò, ó jẹ́ ọmọJósẹ́fù,+ọmọ Hélì, Lúùkù 3:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 ọmọ Ámínádábù,ọmọ Áánì,ọmọ Hésírónì,ọmọ Pérésì,+ọmọ Júdà,+