Nọ́ńbà 1:4, 5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 “Kí ẹ mú ọkùnrin kan látinú ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan; kí ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn jẹ́ olórí agbo ilé bàbá+ rẹ̀. 5 Orúkọ àwọn ọkùnrin tó máa dúró tì yín nìyí: ní ẹ̀yà Rúbẹ́nì, Élísúrì+ ọmọ Ṣédéúrì;
4 “Kí ẹ mú ọkùnrin kan látinú ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan; kí ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn jẹ́ olórí agbo ilé bàbá+ rẹ̀. 5 Orúkọ àwọn ọkùnrin tó máa dúró tì yín nìyí: ní ẹ̀yà Rúbẹ́nì, Élísúrì+ ọmọ Ṣédéúrì;