Ẹ́kísódù 30:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 “Nígbàkigbà tí o bá ka iye àwọn ọmọ Ísírẹ́lì,+ kí kálukú mú ohun tí yóò fi ra ẹ̀mí* rẹ̀ pa dà wá fún Jèhófà nígbà ìkànìyàn náà. Èyí ò ní jẹ́ kí ìyọnu kankan ṣẹlẹ̀ sí wọn nígbà tí wọ́n bá forúkọ wọn sílẹ̀.
12 “Nígbàkigbà tí o bá ka iye àwọn ọmọ Ísírẹ́lì,+ kí kálukú mú ohun tí yóò fi ra ẹ̀mí* rẹ̀ pa dà wá fún Jèhófà nígbà ìkànìyàn náà. Èyí ò ní jẹ́ kí ìyọnu kankan ṣẹlẹ̀ sí wọn nígbà tí wọ́n bá forúkọ wọn sílẹ̀.