ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 38:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Fàdákà àwọn tó forúkọ sílẹ̀ lára àpéjọ náà sì jẹ́ ọgọ́rùn-ún (100) tálẹ́ńtì àti ẹgbẹ̀rún kan ó lé ọgọ́rùn-ún méje àti márùndínlọ́gọ́rin (1,775) ṣékélì, ìwọ̀n ṣékélì ibi mímọ́.*

  • Nọ́ńbà 1:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 “Ẹ ka+ gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì* lọ́kọ̀ọ̀kan,* ní ìdílé-ìdílé, agbo ilé bàbá wọn, kí ẹ fi orúkọ ka gbogbo ọkùnrin.

  • 2 Sámúẹ́lì 24:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Àmọ́ ọkàn* Dáfídì dá a lẹ́bi+ lẹ́yìn tó ti ka iye àwọn èèyàn náà. Dáfídì wá sọ fún Jèhófà pé: “Mo ti dá ẹ̀ṣẹ̀+ ńlá nítorí ohun tí mo ṣe yìí. Ní báyìí, Jèhófà, jọ̀wọ́ dárí ẹ̀ṣẹ̀ ìránṣẹ́ rẹ jì í,+ nítorí mo ti hùwà òmùgọ̀ gan-an.”+

  • 2 Sámúẹ́lì 24:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Nígbà náà, Jèhófà rán àjàkálẹ̀ àrùn+ sí Ísírẹ́lì láti àárọ̀ títí di àkókò tó dá, tí ọ̀kẹ́ mẹ́ta ààbọ̀ (70,000) fi kú+ lára àwọn èèyàn náà láti Dánì títí dé Bíá-ṣébà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́