ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 30:7, 8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Bílíhà, ìránṣẹ́ Réṣẹ́lì tún lóyún lẹ́ẹ̀kan sí i, nígbà tó yá, ó bí ọmọkùnrin kejì fún Jékọ́bù. 8 Réṣẹ́lì wá sọ pé: “Ìjàkadì gidi ni mo bá ẹ̀gbọ́n mi jà. Mo sì ti borí!” Torí náà, ó pe orúkọ rẹ̀ ní Náfútálì.*+

  • Jẹ́nẹ́sísì 46:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Àwọn ọmọ Náfútálì+ ni Jáséélì, Gúnì, Jésérì àti Ṣílẹ́mù.+

  • Nọ́ńbà 2:29, 30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Kí ẹ̀yà Náfútálì wá tẹ̀ lé wọn; Áhírà+ ọmọ Énánì ni ìjòyè àwọn ọmọ Náfútálì. 30 Àwọn tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ nínú àwọn ọmọ ogun rẹ̀ jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́tàléláàádọ́ta ó lé ọgọ́rùn-ún mẹ́rin (53,400).+

  • Nọ́ńbà 26:48
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 48 Àwọn ọmọ Náfútálì+ nìyí ní ìdílé-ìdílé: látọ̀dọ̀ Jáséélì, ìdílé àwọn ọmọ Jáséélì; látọ̀dọ̀ Gúnì, ìdílé àwọn ọmọ Gúnì;

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́