-
Nọ́ńbà 7:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Ní ọjọ́ kọ̀ọ̀kan, kí ìjòyè kọ̀ọ̀kan mú ọrẹ rẹ̀ wá fún ìyàsímímọ́ pẹpẹ náà, ní ọjọ́ kan tẹ̀ lé òmíràn.”
-
-
Nọ́ńbà 7:78Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
78 Ní ọjọ́ kejìlá, Áhírà+ ọmọ Énánì, ìjòyè àwọn ọmọ Náfútálì
-
-
Nọ́ńbà 10:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Áhírà+ ọmọ Énánì ni olórí àwùjọ ẹ̀yà àwọn ọmọ Náfútálì.
-