-
Nọ́ńbà 1:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 “Kí ẹ mú ọkùnrin kan látinú ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan; kí ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn jẹ́ olórí agbo ilé bàbá+ rẹ̀.
-
-
Nọ́ńbà 1:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 ní ẹ̀yà Náfútálì, Áhírà+ ọmọ Énánì.
-
-
Nọ́ńbà 2:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 Kí ẹ̀yà Náfútálì wá tẹ̀ lé wọn; Áhírà+ ọmọ Énánì ni ìjòyè àwọn ọmọ Náfútálì.
-