-
Nọ́ńbà 2:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 Kí ẹ̀yà Náfútálì wá tẹ̀ lé wọn; Áhírà+ ọmọ Énánì ni ìjòyè àwọn ọmọ Náfútálì.
-
-
Nọ́ńbà 10:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Áhírà+ ọmọ Énánì ni olórí àwùjọ ẹ̀yà àwọn ọmọ Náfútálì.
-