-
Nọ́ńbà 2:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Kí ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì wá tẹ̀ lé wọn; Ábídánì+ ọmọ Gídéónì ni ìjòyè àwọn ọmọ Bẹ́ńjámínì.
-
-
Nọ́ńbà 10:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Ábídánì+ ọmọ Gídéónì sì ni olórí àwùjọ ẹ̀yà àwọn ọmọ Bẹ́ńjámínì.
-