-
Nọ́ńbà 1:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 “Kí ẹ mú ọkùnrin kan látinú ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan; kí ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn jẹ́ olórí agbo ilé bàbá+ rẹ̀.
-
-
Nọ́ńbà 1:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 ní ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì, Ábídánì+ ọmọ Gídéónì;
-
-
Nọ́ńbà 2:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Kí ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì wá tẹ̀ lé wọn; Ábídánì+ ọmọ Gídéónì ni ìjòyè àwọn ọmọ Bẹ́ńjámínì.
-