Nọ́ńbà 7:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àwọn ìjòyè náà wá mú ọrẹ wọn wá síbi ìyàsímímọ́*+ pẹpẹ lọ́jọ́ tí wọ́n fòróró yàn án. Nígbà tí àwọn ìjòyè náà mú ọrẹ wọn wá síwájú pẹpẹ, Ẹ́sírà 2:68 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 68 Nígbà tí wọ́n dé ilé Jèhófà ní Jerúsálẹ́mù, lára àwọn olórí agbo ilé ṣe ọrẹ àtinúwá+ fún ilé Ọlọ́run tòótọ́, kí wọ́n lè tún un kọ́* sí àyè rẹ̀.+
10 Àwọn ìjòyè náà wá mú ọrẹ wọn wá síbi ìyàsímímọ́*+ pẹpẹ lọ́jọ́ tí wọ́n fòróró yàn án. Nígbà tí àwọn ìjòyè náà mú ọrẹ wọn wá síwájú pẹpẹ,
68 Nígbà tí wọ́n dé ilé Jèhófà ní Jerúsálẹ́mù, lára àwọn olórí agbo ilé ṣe ọrẹ àtinúwá+ fún ilé Ọlọ́run tòótọ́, kí wọ́n lè tún un kọ́* sí àyè rẹ̀.+