Léfítíkù 8:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Mú Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀+ pẹ̀lú àwọn aṣọ,+ òróró àfiyanni,+ akọ màlúù ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀, àgbò méjì àti apẹ̀rẹ̀ búrẹ́dì aláìwú,+ 3 kí o sì mú kí gbogbo àpéjọ náà kóra jọ sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé.”
2 “Mú Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀+ pẹ̀lú àwọn aṣọ,+ òróró àfiyanni,+ akọ màlúù ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀, àgbò méjì àti apẹ̀rẹ̀ búrẹ́dì aláìwú,+ 3 kí o sì mú kí gbogbo àpéjọ náà kóra jọ sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé.”