Nọ́ńbà 3:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 “Wò ó! Ní tèmi, mo mú àwọn ọmọ Léfì látinú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì dípò gbogbo àkọ́bí* àwọn ọmọ Ísírẹ́lì,+ àwọn ọmọ Léfì yóò sì di tèmi.
12 “Wò ó! Ní tèmi, mo mú àwọn ọmọ Léfì látinú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì dípò gbogbo àkọ́bí* àwọn ọmọ Ísírẹ́lì,+ àwọn ọmọ Léfì yóò sì di tèmi.