-
Nọ́ńbà 19:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 “‘Òfin tí ẹ máa tẹ̀ lé nìyí tí ẹnì kan bá kú sínú àgọ́: Ẹnikẹ́ni tó bá wọnú àgọ́ náà àti ẹnikẹ́ni tó ti wà nínú àgọ́ náà tẹ́lẹ̀ máa jẹ́ aláìmọ́ fún ọjọ́ méje.
-
-
Nọ́ńbà 19:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Ẹnikẹ́ni tó bá wà ní pápá tó sì fara kan ẹni tí wọ́n fi idà pa tàbí òkú tàbí egungun èèyàn tàbí ibi ìsìnkú yóò jẹ́ aláìmọ́ fún ọjọ́ méje.+
-