ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 1:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Wọ́n pe gbogbo àwọn èèyàn náà jọ ní ọjọ́ kìíní oṣù kejì, kí wọ́n lè forúkọ sílẹ̀ lọ́kọ̀ọ̀kan, ní ìdílé-ìdílé àti agbo ilé bàbá wọn, láti ẹni ogún (20) ọdún sókè,+

  • Diutarónómì 29:10, 11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 “Gbogbo yín lẹ dúró níwájú Jèhófà Ọlọ́run yín lónìí, àwọn olórí ẹ̀yà yín, àwọn àgbààgbà yín, àwọn aṣojú yín, gbogbo ọkùnrin Ísírẹ́lì, 11 àwọn ọmọ yín, àwọn ìyàwó yín,+ àwọn àjèjì tó wà nínú ibùdó yín,+ látorí ẹni tó ń bá yín ṣẹ́gi dórí ẹni tó ń bá yín fa omi.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́