ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 18:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Àmọ́ kí o yan àwọn ọkùnrin tó kúnjú ìwọ̀n nínú àwọn èèyàn náà,+ àwọn tó bẹ̀rù Ọlọ́run, tí wọ́n ṣeé fọkàn tán, tí wọ́n sì kórìíra èrè tí kò tọ́,+ kí o wá fi àwọn yìí ṣe olórí wọn, kí wọ́n jẹ́ olórí ẹgbẹẹgbẹ̀rún, olórí ọgọ́rọ̀ọ̀rún, olórí àràádọ́ta àti olórí mẹ́wàá-mẹ́wàá.+

  • Nọ́ńbà 1:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Àwọn yìí ni wọ́n pè látinú àpéjọ náà. Wọ́n jẹ́ ìjòyè+ nínú ẹ̀yà àwọn bàbá wọn, olórí ẹgbẹẹgbẹ̀rún ní Ísírẹ́lì.”+

  • Nọ́ńbà 7:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 àwọn ìjòyè Ísírẹ́lì,+ àwọn olórí agbo ilé bàbá wọn mú ọrẹ wá. Àwọn ìjòyè yìí látinú àwọn ẹ̀yà, tí wọ́n darí ìforúkọsílẹ̀ náà

  • Diutarónómì 1:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Torí náà, mo mú àwọn olórí ẹ̀yà yín, àwọn ọkùnrin tó jẹ́ ọlọ́gbọ́n, tí wọ́n sì ní ìrírí, mo yàn wọ́n ṣe olórí yín, olórí ẹgbẹẹgbẹ̀rún, olórí ọgọ́rọ̀ọ̀rún, olórí àràádọ́ta, olórí àwọn mẹ́wàá-mẹ́wàá àti àwọn aṣojú nínú àwọn ẹ̀yà yín.+

  • Diutarónómì 5:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 “Àmọ́ gbàrà tí ẹ gbọ́ ohùn tó ń tinú òkùnkùn náà jáde, nígbà tí iná ń jó ní òkè náà,+ gbogbo olórí ẹ̀yà yín àti àwọn àgbààgbà wá sọ́dọ̀ mi.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́