Nọ́ńbà 10:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Tí wọ́n bá fun kàkàkí méjèèjì, kí gbogbo àpéjọ náà wá sọ́dọ̀ rẹ ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé.+