Nọ́ńbà 2:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe gbogbo ohun tí Jèhófà pa láṣẹ fún Mósè. Báyìí ni wọ́n ṣe ń pàgọ́, lọ́nà mẹ́ta-mẹ́ta tí wọ́n pín ẹ̀yà wọn sí,+ tí wọ́n sì máa ń tú àgọ́ wọn ká,+ ní ìdílé-ìdílé àti agbo ilé bàbá wọn.
34 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe gbogbo ohun tí Jèhófà pa láṣẹ fún Mósè. Báyìí ni wọ́n ṣe ń pàgọ́, lọ́nà mẹ́ta-mẹ́ta tí wọ́n pín ẹ̀yà wọn sí,+ tí wọ́n sì máa ń tú àgọ́ wọn ká,+ ní ìdílé-ìdílé àti agbo ilé bàbá wọn.