Nọ́ńbà 2:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Kí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pàgọ́ síbi tí wọ́n pín àwọn ẹ̀yà wọn sí ní mẹ́ta-mẹ́ta,+ kí ọkùnrin kọ̀ọ̀kan pàgọ́ síbi àkọlé* agbo ilé bàbá rẹ̀. Kí àgọ́ wọn dojú kọ àgọ́ ìpàdé, kí wọ́n pàgọ́ yí i ká.
2 “Kí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pàgọ́ síbi tí wọ́n pín àwọn ẹ̀yà wọn sí ní mẹ́ta-mẹ́ta,+ kí ọkùnrin kọ̀ọ̀kan pàgọ́ síbi àkọlé* agbo ilé bàbá rẹ̀. Kí àgọ́ wọn dojú kọ àgọ́ ìpàdé, kí wọ́n pàgọ́ yí i ká.