Nọ́ńbà 11:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Jèhófà wá dá Mósè lóhùn pé: “Kó àádọ́rin (70) ọkùnrin jọ fún mi nínú àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì, àwọn tí o mọ̀ pé wọ́n jẹ́* àgbààgbà àti olórí láàárín àwọn èèyàn náà,+ kí o mú wọn lọ sí àgọ́ ìpàdé, kí wọ́n sì dúró níbẹ̀ pẹ̀lú rẹ.
16 Jèhófà wá dá Mósè lóhùn pé: “Kó àádọ́rin (70) ọkùnrin jọ fún mi nínú àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì, àwọn tí o mọ̀ pé wọ́n jẹ́* àgbààgbà àti olórí láàárín àwọn èèyàn náà,+ kí o mú wọn lọ sí àgọ́ ìpàdé, kí wọ́n sì dúró níbẹ̀ pẹ̀lú rẹ.