-
Sáàmù 78:26, 27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Ó ru ẹ̀fúùfù ìlà oòrùn sókè ní ọ̀run,
Ó sì mú kí ẹ̀fúùfù gúúsù fẹ́ nípasẹ̀ agbára rẹ̀.+
27 Ó rọ̀jò ẹran lé wọn lórí bí eruku,
Àwọn ẹyẹ bí iyanrìn etíkun.
-