-
Nọ́ńbà 7:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Ní ọjọ́ kọ̀ọ̀kan, kí ìjòyè kọ̀ọ̀kan mú ọrẹ rẹ̀ wá fún ìyàsímímọ́ pẹpẹ náà, ní ọjọ́ kan tẹ̀ lé òmíràn.”
-
-
Nọ́ńbà 7:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Ní ọjọ́ kejì, Nétánélì+ ọmọ Súárì, ìjòyè Ísákà mú ọrẹ wá.
-
-
Nọ́ńbà 10:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Nétánélì+ ọmọ Súárì ni olórí àwùjọ ẹ̀yà àwọn ọmọ Ísákà.
-