-
Nọ́ńbà 1:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 “Kí ẹ mú ọkùnrin kan látinú ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan; kí ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn jẹ́ olórí agbo ilé bàbá+ rẹ̀.
-
-
Nọ́ńbà 1:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 ní ẹ̀yà Ísákà, Nétánélì+ ọmọ Súárì;
-
-
Nọ́ńbà 2:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Kí ẹ̀yà Ísákà pàgọ́ sí ẹ̀gbẹ́ wọn; Nétánélì+ ọmọ Súárì ni ìjòyè àwọn ọmọ Ísákà.
-
-
Nọ́ńbà 10:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Nétánélì+ ọmọ Súárì ni olórí àwùjọ ẹ̀yà àwọn ọmọ Ísákà.
-