-
Nọ́ńbà 14:33, 34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 Ogójì (40) ọdún+ ni àwọn ọmọ yín fi máa ṣe olùṣọ́ àgùntàn nínú aginjù, wọ́n sì máa jìyà ìwà àìṣòótọ́ tí ẹ hù* títí ẹni tó kẹ́yìn nínú yín fi máa kú sínú aginjù.+ 34 Ogójì (40) ọjọ́+ lẹ fi ṣe amí ilẹ̀ náà, àmọ́ ogójì (40) ọdún+ lẹ máa fi jìyà ẹ̀ṣẹ̀ yín, ọjọ́ kan fún ọdún kan, ọjọ́ kan fún ọdún kan, ẹ ó wá mọ ohun tó túmọ̀ sí láti ta kò mí.*
-