Nọ́ńbà 32:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Jèhófà bínú gidigidi sí Ísírẹ́lì, ó sì mú kí wọ́n fi ogójì (40) ọdún+ rìn kiri nínú aginjù, títí gbogbo ìran tó ń hùwà ibi lójú Jèhófà fi pa run.+ Jóṣúà 14:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Bí Jèhófà ṣe ṣèlérí,+ ó dá ẹ̀mí mi sí+ jálẹ̀ ọdún márùndínláàádọ́ta (45) yìí, látìgbà tí Jèhófà ti ṣe ìlérí yìí fún Mósè, nígbà tí Ísírẹ́lì rìn nínú aginjù;+ èmi náà rèé lónìí, lẹ́ni ọdún márùndínláàádọ́rùn-ún (85).
13 Jèhófà bínú gidigidi sí Ísírẹ́lì, ó sì mú kí wọ́n fi ogójì (40) ọdún+ rìn kiri nínú aginjù, títí gbogbo ìran tó ń hùwà ibi lójú Jèhófà fi pa run.+
10 Bí Jèhófà ṣe ṣèlérí,+ ó dá ẹ̀mí mi sí+ jálẹ̀ ọdún márùndínláàádọ́ta (45) yìí, látìgbà tí Jèhófà ti ṣe ìlérí yìí fún Mósè, nígbà tí Ísírẹ́lì rìn nínú aginjù;+ èmi náà rèé lónìí, lẹ́ni ọdún márùndínláàádọ́rùn-ún (85).