Émọ́sì 2:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 ‘Ṣùgbọ́n èmi ni mo pa Ámórì rẹ́ ní ìṣojú wọn,+Ẹni tó ga bí igi kédárì, tó sì ní agbára bí àwọn igi ràgàjì;*Mo pa èso rẹ̀ run lókè àti gbòǹgbò rẹ̀ nísàlẹ̀.+
9 ‘Ṣùgbọ́n èmi ni mo pa Ámórì rẹ́ ní ìṣojú wọn,+Ẹni tó ga bí igi kédárì, tó sì ní agbára bí àwọn igi ràgàjì;*Mo pa èso rẹ̀ run lókè àti gbòǹgbò rẹ̀ nísàlẹ̀.+