Sáàmù 78:40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 Ẹ wo iye ìgbà tí wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí i ní aginjù,+Tí wọ́n sì bà á nínú jẹ́ ní aṣálẹ̀!+