-
Hébérù 3:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Torí, àwọn wo ló gbọ́, síbẹ̀ tí wọ́n mú un bínú gidigidi? Ní tòótọ́, ṣebí gbogbo àwọn tí Mósè kó jáde ní Íjíbítì ni?+