Nọ́ńbà 14:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 “‘“Àwọn ọmọ yín tí ẹ sọ pé wọ́n máa kó+ lẹ́rú ni màá mú débẹ̀, wọ́n á sì mọ ilẹ̀ tí ẹ kọ̀+ náà. Diutarónómì 1:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Àmọ́, àwọn ọmọ yín tí ẹ sọ pé wọ́n máa kó lẹ́rú+ àti àwọn ọmọ yín tí wọn ò mọ rere yàtọ̀ sí búburú lónìí ni wọ́n máa wọ ibẹ̀, àwọn ni màá sì fún ní ilẹ̀ náà kó lè di tiwọn.+
39 Àmọ́, àwọn ọmọ yín tí ẹ sọ pé wọ́n máa kó lẹ́rú+ àti àwọn ọmọ yín tí wọn ò mọ rere yàtọ̀ sí búburú lónìí ni wọ́n máa wọ ibẹ̀, àwọn ni màá sì fún ní ilẹ̀ náà kó lè di tiwọn.+