3 Kí ló dé tí Jèhófà fẹ́ mú wa wá sí ilẹ̀ yìí kí wọ́n lè fi idà+ pa wá? Wọ́n á kó+ àwọn ìyàwó wa àti àwọn ọmọ wa lẹ́rú. Ǹjẹ́ kò ní dáa ká pa dà sí Íjíbítì?”+
39 Àmọ́, àwọn ọmọ yín tí ẹ sọ pé wọ́n máa kó lẹ́rú+ àti àwọn ọmọ yín tí wọn ò mọ rere yàtọ̀ sí búburú lónìí ni wọ́n máa wọ ibẹ̀, àwọn ni màá sì fún ní ilẹ̀ náà kó lè di tiwọn.+