-
Nọ́ńbà 21:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Nígbà tí ọba ìlú Árádì+ ti ilẹ̀ Kénáánì, tó ń gbé Négébù gbọ́ pé Ísírẹ́lì ti ń gba ọ̀nà Átárímù bọ̀, ó gbéjà ko Ísírẹ́lì, ó sì kó lára wọn lọ.
-
-
Diutarónómì 1:44Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
44 Àwọn Ámórì tí wọ́n ń gbé ní òkè náà sì jáde wá pàdé yín, wọ́n lé yín dà nù bí oyin ṣe máa ń ṣe, wọ́n sì tú yín ká láti Séírì títí lọ dé Hóómà.
-