-
Nọ́ńbà 33:40Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
40 Ó ṣẹlẹ̀ pé ọba Árádì,+ ọmọ Kénáánì tó ń gbé ní Négébù, ní ilẹ̀ Kénáánì gbọ́ pé àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ti ń bọ̀.
-
-
Jóṣúà 12:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 ọba Hóómà, ọ̀kan; ọba Árádì, ọ̀kan;
-