-
Léfítíkù 24:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 “Mú ẹni tó ṣépè náà wá sí ẹ̀yìn ibùdó, kí gbogbo àwọn tó gbọ́ ohun tó sọ gbé ọwọ́ wọn lé e lórí, kí gbogbo àpéjọ náà sì sọ ọ́ lókùúta.+
-