Nọ́ńbà 15:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Nígbà tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wà ní aginjù, wọ́n rí ọkùnrin kan tó ń ṣa igi ní ọjọ́ Sábáàtì.+ Nọ́ńbà 15:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Ẹ gbọ́dọ̀ pa+ ọkùnrin náà, kí gbogbo àpéjọ sọ ọ́ ní òkúta ní ẹ̀yìn ibùdó.”+ Diutarónómì 17:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ọwọ́ àwọn ẹlẹ́rìí náà ni kó kọ́kọ́ bà á tí wọ́n bá fẹ́ pa á, lẹ́yìn náà kí gbogbo èèyàn dáwọ́ jọ láti pa á. Kí o mú ohun tó burú kúrò láàárín rẹ.+
35 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Ẹ gbọ́dọ̀ pa+ ọkùnrin náà, kí gbogbo àpéjọ sọ ọ́ ní òkúta ní ẹ̀yìn ibùdó.”+
7 Ọwọ́ àwọn ẹlẹ́rìí náà ni kó kọ́kọ́ bà á tí wọ́n bá fẹ́ pa á, lẹ́yìn náà kí gbogbo èèyàn dáwọ́ jọ láti pa á. Kí o mú ohun tó burú kúrò láàárín rẹ.+