-
Nọ́ńbà 26:7-9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Ìwọ̀nyí ni ìdílé àwọn ọmọ Rúbẹ́nì, iye àwọn tí wọ́n sì forúkọ wọn sílẹ̀ jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́tàlélógójì ó lé ọgọ́rùn-ún méje àti ọgbọ̀n (43,730).+
8 Ọmọ Pálù ni Élíábù. 9 Àwọn ọmọ Élíábù ni: Némúẹ́lì, Dátánì àti Ábírámù. Dátánì àti Ábírámù yìí ni wọ́n yàn nínú àpéjọ náà, àwọn ló bá Mósè+ àti Áárónì jà pẹ̀lú àwọn tí Kórà kó jọ+ nígbà tí wọ́n bá Jèhófà+ jà.
-