ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 16:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Ó sì sọ fún Kórà àti gbogbo àwọn tó ń tì í lẹ́yìn pé: “Tó bá di àárọ̀, Jèhófà máa jẹ́ ká mọ ẹni tó jẹ́ tirẹ̀+ àti ẹni tó jẹ́ mímọ́ àti ẹni tó gbọ́dọ̀ máa sún mọ́ ọn,+ ẹnikẹ́ni tó bá sì yàn+ ló máa sún mọ́ ọn.

  • Nọ́ńbà 16:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Nígbà tí Kórà kó àwọn tó ń tì í lẹ́yìn,+ tí wọ́n jọ ń ta kò wọ́n jọ sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé, ògo Jèhófà fara han gbogbo àpéjọ+ náà.

  • Diutarónómì 11:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 tàbí ohun tó ṣe sí Dátánì àti Ábírámù, àwọn ọmọ Élíábù ọmọ Rúbẹ́nì níṣojú gbogbo Ísírẹ́lì, nígbà tí ilẹ̀ lanu tó sì gbé wọn mì pẹ̀lú agbo ilé wọn àti àwọn àgọ́ wọn àti gbogbo ohun alààyè tó tẹ̀ lé wọn.+

  • Sáàmù 106:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Ni ilẹ̀ bá lanu, ó gbé Dátánì mì,

      Ó sì bo àwọn tó kóra jọ sọ́dọ̀ Ábírámù.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́