Ẹ́kísódù 28:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 “Kí o mú Áárónì ẹ̀gbọ́n rẹ, pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ̀ látinú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, kí wọ́n lè di àlùfáà mi,+ Áárónì,+ pẹ̀lú Nádábù àti Ábíhù,+ Élíásárì àti Ítámárì,+ àwọn ọmọ Áárónì.+ Nọ́ńbà 17:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ẹni tí ọ̀pá rẹ̀ bá rúwé* ni ẹni tí mo yàn,+ màá sì pa àwọn ọmọ Ísírẹ́lì lẹ́nu mọ́ kí wọ́n má bàa kùn sí mi+ mọ́, bí wọ́n ṣe ń kùn sí ẹ̀yin náà.”+ Sáàmù 105:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Ó rán Mósè ìránṣẹ́ rẹ̀+Àti Áárónì,+ ẹni tí ó yàn.
28 “Kí o mú Áárónì ẹ̀gbọ́n rẹ, pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ̀ látinú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, kí wọ́n lè di àlùfáà mi,+ Áárónì,+ pẹ̀lú Nádábù àti Ábíhù,+ Élíásárì àti Ítámárì,+ àwọn ọmọ Áárónì.+
5 Ẹni tí ọ̀pá rẹ̀ bá rúwé* ni ẹni tí mo yàn,+ màá sì pa àwọn ọmọ Ísírẹ́lì lẹ́nu mọ́ kí wọ́n má bàa kùn sí mi+ mọ́, bí wọ́n ṣe ń kùn sí ẹ̀yin náà.”+