Nọ́ńbà 3:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Kí o fún Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ ní àwọn ọmọ Léfì. Àwọn ni a fi fúnni, a fún un látinú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+ Nọ́ńbà 3:41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 41 Èmi ni Jèhófà, kí o mú àwọn ọmọ Léfì fún mi dípò gbogbo àkọ́bí nínú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì,+ kí o sì mú ẹran ọ̀sìn àwọn ọmọ Léfì dípò gbogbo àkọ́bí ẹran ọ̀sìn àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.”+
9 Kí o fún Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ ní àwọn ọmọ Léfì. Àwọn ni a fi fúnni, a fún un látinú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+
41 Èmi ni Jèhófà, kí o mú àwọn ọmọ Léfì fún mi dípò gbogbo àkọ́bí nínú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì,+ kí o sì mú ẹran ọ̀sìn àwọn ọmọ Léfì dípò gbogbo àkọ́bí ẹran ọ̀sìn àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.”+