ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 8:15, 16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Lẹ́yìn náà, kí àwọn ọmọ Léfì wọlé, kí wọ́n sì máa ṣiṣẹ́ ní àgọ́ ìpàdé. Bí o ṣe máa wẹ̀ wọ́n mọ́ nìyí, tí wàá sì mú wọn wá* bí ọrẹ fífì. 16 Àwọn ni a fi fúnni, a fún mi látinú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì. Èmi yóò mú wọn fún ara mi dípò gbogbo àkọ́bí* àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+

  • Nọ́ńbà 18:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Èmi fúnra mi ti mú àwọn arákùnrin yín, àwọn ọmọ Léfì, látinú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, mo sì fi wọ́n ṣe ẹ̀bùn fún yín.+ A ti fi wọ́n fún Jèhófà kí wọ́n lè máa bójú tó iṣẹ́ tó jẹ mọ́ àgọ́ ìpàdé.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́