Nọ́ńbà 16:46 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 46 Mósè wá sọ fún Áárónì pé: “Mú ìkóná, kí o fi iná sí i látorí pẹpẹ,+ kí o fi tùràrí sí i, kí o wá yára lọ sọ́dọ̀ àwọn èèyàn náà, kí o sì ṣe ètùtù fún wọn,+ torí pé Jèhófà ti bínú sí wọn gan-an. Àjàkálẹ̀ àrùn ti bẹ̀rẹ̀!”
46 Mósè wá sọ fún Áárónì pé: “Mú ìkóná, kí o fi iná sí i látorí pẹpẹ,+ kí o fi tùràrí sí i, kí o wá yára lọ sọ́dọ̀ àwọn èèyàn náà, kí o sì ṣe ètùtù fún wọn,+ torí pé Jèhófà ti bínú sí wọn gan-an. Àjàkálẹ̀ àrùn ti bẹ̀rẹ̀!”