-
Ẹ́kísódù 34:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Kí ẹ fi àgùntàn ra àkọ́bí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ pa dà. Àmọ́ tí ẹ ò bá rà á pa dà, kí ẹ ṣẹ́ ọrùn rẹ̀. Kí ẹ ra gbogbo àkọ́bí nínú àwọn ọmọkùnrin yín pa dà.+ Ẹnikẹ́ni ò gbọ́dọ̀ wá síwájú mi lọ́wọ́ òfo.
-
-
Léfítíkù 27:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Tó bá wà lára àwọn ẹran aláìmọ́, tó sì tún un rà pa dà gẹ́gẹ́ bí iye tí wọ́n dá lé e, kó fi ìdá márùn-ún rẹ̀ kún un.+ Àmọ́ tí kò bá rà á pa dà, iye tí wọ́n dá lé e ni kí wọ́n tà á.
-